Ìkójáde àwọn ojúewé

Jump to navigation Jump to search

Ẹ le ṣàkójáde ìkọ̀rọ̀ àti ìtàn àtúnṣe ojúewé pàtó kan tàbí àpapọ̀ àwọn ojúewé tí a fi XML yí. Èyí ṣe é kówọlé sínú wiki míràn pẹ̀lú MediaWiki láti orí ìkówọlé ojúewé.

Láti ṣàkójáde àwọn ojúewé, ẹ tẹ àkọlé wọn sínú àpótí ọ̀rọ̀ ìsàlẹ̀, àkọlé kan lórí ìlà kan, kí ẹ sì sọ bóyá ẹ fẹ́ àtúnyẹ̀wò ìwòyí àti àwọn àtúnyẹ̀wò tó ti pẹ́, pẹ̀lú ìlà ìtàn ojúewé, tàbí àtúnyẹ̀wò ìwòyí pẹ̀lú ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ nípa àtúnṣe tó gbẹ̀yìn.

Ẹ tún le lo àjápọ̀, fún àpẹrẹ Pàtàkì:Export/Ojúewé Àkọ́kọ́ fún ojúewé "Ojúewé Àkọ́kọ́".