Ojo N Ro:

Lát'ọwọ́ Wikibooks

Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Ojo N Ro

Ojo N Ro,

Sere ninu ile

Ma wo inu ojo

Ki aso re

Ma ba tutu

Ki otutu

Ma ba mu e.

Jẹ́ kíkójáde láti "http://yo.wikibooks.org/wiki/Ojo_N_Ro:"
Àwọn irinṣẹ́ àdáni