Ojo N Ro:
Jump to navigation
Jump to search
Ojo N Ro
Ojo N Ro,
Sere ninu ile
Ma wo inu ojo
Ki aso re
Ma ba tutu
Ki otutu
Ma ba mu e.
Ojo N Ro
Ojo N Ro,
Sere ninu ile
Ma wo inu ojo
Ki aso re
Ma ba tutu
Ki otutu
Ma ba mu e.